Alaye ni ẹkunrẹrẹ waye ninu idanilẹkọ yii lori ẹkọ ti o rọ mọ gbogbo ẹni ti n se isẹ sin eniyan.
Awọn Ẹko ti o rọ mọ Ọmọ-ọdọ tabi Osisẹ ti a gba si isẹ - (Èdè Yorùbá)
Gba-fi-pamọ (Amaanah) Itumọ rẹ ati ohun ti o ko sinu - (Èdè Yorùbá)
Alaye ohun ti o njẹ gba-fi-pamọ lati inu Alukuraani ati Sunnah ati alaye gbogbo ohun ti o ko si abẹ gbafipamọ.
Asigbọ lori Akoko Irun Jimọh - (Èdè Yorùbá)
Idanilẹkọ yii se alaye ọrọ awọn onimimọ ti o da lori igba ti o yẹ ki a maa ki Irun Jimọh, ni idahun si asigbọye ẹsin eyi ti o n waye lati ọwọ ikọ awọn ọdọ Musulumi kan ti wọn ngbe Irun Jimọh duro ni aago mẹsan awurọ.
Iroyin Ina ati Awọn ohun ti ngbe Eniyan wọ ọ - (Èdè Yorùbá)
1- Idanilẹkọ ni agbegbe yii sọ awọn ayọka Alukuraani ati ẹgbawa hadisi ti nse apejuwe bi Ina se ri. 2- Alaye awọn okunfa ti o maa nmu eniyan wọ Ina, awọn okunfa yii pin si meji: (1) Okunfa ti o maa nmu eniyan bẹ ninu Ina lọ gbere, (2) okunfa....
Iroyin Alujannah ati Awọn Olugbe rẹ - (Èdè Yorùbá)
1- Idanilẹkọ yii sọ nipa oniranran apejuwe nipa ibugbe Alujannah gẹgẹ bi awọn apejuwe yii se wa lati inu Alukuraani ati Sunnah Ojisẹ Ọlọhun. 2- Alaye lori awọn isẹ ti o maa nse okunfa wiwọ Alujannah gẹgẹ bi Ọlọhun ti se se iroyin rẹ lati inu Alukuraani ati Sunna.
Ẹran ikomọjade ati awọn idajọ ti o rọ mọ ọ - (Èdè Yorùbá)
Alaye ohun ti o njẹ ẹran ikomọjade ati awọn ẹri ti o tọka si i ninu Sunna. Alaye awọn idajọ ẹran ikomọjade pẹlu sisọ awọn majẹmu ti o rọ mọ ọ. Abala yii ni oludanilẹkọ ti jẹ ki a mọ boya a le se ẹran ikomọjade ni ọbẹ, ki a....
Awọn Aisedeede ti o maa nsẹlẹ pupọ lori Irun - (Èdè Yorùbá)
Pataki irun kiki ati wipe ohun ni akọkọ ohun ti Musulumi yoo se isiro rẹ ni ọjọ ajinde. Diẹ ninu awọn aisedeede naa gẹgẹ bii: aifarabalẹ, wiwo ọtun wosi lori irun ati bẹẹbẹẹ lọ.
Idanilẹkọ yii da lori awọn Iwa Abiyì ti a le kọ ẹkọ rẹ lati ara Anọbi Muhammad [Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a]
Ọsọ Obinrin ninu Ẹsin Islam - (Èdè Yorùbá)
Idajọ ti o rọ mọ ọsọ obinrin sise pẹlu ojupọnna ti obinrin le gba se ọsọ ninu Islam
Suuru ati erenje ti o nbẹ fun un - (Èdè Yorùbá)
Ninu idanilẹkọ yii: (1) Pataki suuru sise. (2) Ọna maarun ti suuru pin si. (3) Ẹsan rere ti nbẹ nibi suuru sise.
Tituuba nibi Ẹsẹ ati awọn majẹmu rẹ - (Èdè Yorùbá)
Alaye lori awọn majẹmu wiwa tituuba lọsi ọdọ Ọlọhun
Ẹsẹ ati Oripa rẹ lori igbesi aye ẹda - (Èdè Yorùbá)
Ohun ti o njẹ ẹsẹ, okunfa rẹ ati oripa ẹsẹ dida lori ẹnikọọkan

API
