Eyi ni alaye awon Hadisi ti o n so nipa awon ojo ti Shari’ah ko fun Musulumi lati maa gba aawe ninu won ati awon eko esin ti o ro mo won.
Idajo Esin Lori Gbigba Aawe ni Ojo Jimoh - (Èdè Yorùbá)
Alaye Ibere Suratu Bakora - (Èdè Yorùbá)
Alaye die ninu awon Aayah ibere Suratu Bakora pelu alaye ekunrere lori itumo “Idaayah” ati awon nkan miran.
Yiyo Saka - (Èdè Yorùbá)
Oro nipa awon ohun ti a maa nyo Saka ninu won, ati oundiwon ti a o yo ninu awon nkan ti Saka wo, Olubanisoro si bere pelu Aayah Alukuraani ti o nso nipa ijiya ti nbe fun awon ti won maa nko dukia jo laiyo Saka ninu re.
Awon Iroyin Jije Eni Olohun - (Èdè Yorùbá)
Oniwaasi so wipe awon majemu meta kan wa fun jije eni Olohun (i) Ki eniyan so asepo laarin ara re ati Olohun re (ii) Ki o so asepo laarin oun ati emi ara re (iii) Ki o so asepo laarin oun ati awujo re.
1- Idanileko yi soro nipa bi arinrin-ajo ati alaare yoo se maa ki irun won laini fi wole tabi lo o lara tayo asiko re. 2- Kiki irun rakah merin ni meji ni ori irinajo ati ki alaare fi aawe sile ninu osu Ramadan ki o si gba a pada....
Idajo Islam lori Odun Ayajo Ojo Ololufe (Valentine Day) - (Èdè Yorùbá)
1- Ibanisoro yii se alaye ibi ti Odun ayajo ojo ololufe (Valentine) ti wa, ati Idajo Islam lori re. 2- Eleyi ni akotan lori oro nipa odun ayajo ojo ololufe (Valentine).
Eto Oko ati Aya ninu Islam - (Èdè Yorùbá)
Ibanisoro se alaye awon eto wonyi: (i) Eto oko lori aya, (ii) Eto Aya lori oko, (iii) Eto ti awon mejeeji ni si ara won.
Awon apo-iwe ti ohun fun kika idamewa igbeyin ninu alukurani alaponle, awon naa ni: eleekeji-din-logbon, eleekokan-din-logbon ati ogbon, pelu itumo re ni ede yoruba pelu ohun ti o dun, ti o wu eti gbo.
Awon Okunfa Isubu Oro-aje Orile-ede - (Èdè Yorùbá)
Iyapa Olohun Allah ati owo ele ni okunfa meji ti o lagbara julo fun isubu oro-aje, imoran si tun waye lori awon ona abayo si isoro yii.
Awon Eko Pataki Nibi Ogun Khandak - (Èdè Yorùbá)
Alaye ohun ti o se okunfa ogun yii ati awon isele ti o waye nibi sise ipalemo fun ogun naa eyi ti o je eri ododo lori wipe Annabi Muhammad ojise Olohun ni. Alaye si tun waye lori aranse ti Olohun se fun ojise Re ninu ogun naa.
Itumo Ki Oko o Ko Iyawo re Sile ati Awon Aburu ti o Wa Nibe - (Èdè Yorùbá)
Ibanisoro yi mu idahun wa lori awon ibeere wonyi: Kinni itumo tolaaki ati itumo Khulkhu, agbara wo ni ile ejo ni lati se onpinya laarin oko ati aya atipe kinni aburu ti o wa nibi ki onpinya sele laarin oko ati aya.
Itumo Igberaga - (Èdè Yorùbá)
Alaye ohun ti a n pe ni igberaga ohun naa ni ki eniyan maa se atako ododo ti o fi oju han ati yiyepere awon eniyan miran.

API
