Musulumi ni mi
Musulumi ni mi - (Èdè Yorùbá)
ALAYE NIPA ESIN ISLAAM NISOKI - (Èdè Yorùbá)
No Description
Itumo ijeri mejeeji ati Pataki won: akosile yi so ni soki itumo ijeri mejeeji ati bi o ti se pataki ki Musulumi mo paapaa re pelu ki o ni adisokan ti o rinle fun itumo re
Ipo Irun Ninu Islam - (Èdè Yorùbá)
Akosile yi so nipa bi irun kiki ti se pataki to ninu esin Islam, ohun ni origun ti o lola julo leyin ijeri mejeeji, ohun naa si ni ise ti erusin maa n se ti o loore julo leyin won.
Ise Ijosin Afokanse Ni Ipile Esin - (Èdè Yorùbá)
Ise ijosin afokanse ni o se pataki ju lo, eyi ti o je wipe Olohun ko ni gba ise miran ti ko ba si nibe. Itumo ise ijosin afokanse ni akosile yi da le lori.
Ola Ti O Nbe Nibi Irun Kiki Ati Awon Anfaani Re - (Èdè Yorùbá)
Oore ti o po pupo ni o wa nibi irun kiki fun Musulumi. Ohun ni ona ti o dara julo lati wa asunmo si odo Olohun, o si maa nse okunfa aforiji fun Musulumi, bakannaa ni o je oluranlowo fun erusin lati wo ogba idera (al-Jannah).
Itumo Gbolohun (As-salaf) - (Èdè Yorùbá)
Alaye ranpe nipa gbolohun (as-salaf) pelu die ninu oro awon onimimo.
Akosile yi se alaye ni ekunrere lori hadiisi eleekesan ninu tira Arbaiina Nawawiyya, o si so opolopo ninu awon anfaani ti o ye ki Musulumi ni imo nipa re ninu hadiisi naa.
Fun oriire ni aye yi ati ni orun, oranyan ni fun Musulumi ki o mo wipe Al-kurani ati Sunna ni ohun yoo maa seri si fun gbogbo oro esin re. Eleyi si ni isesi awon eni isiwaju lati ori awon Saabe Ojise Olohun ati awon ti won tele ilana won.....
Itumọ Wiwa Alubarika ati Awọn Ipin rẹ - (Èdè Yorùbá)
Akosile yi so oro lori ohun ti a npe ni wiwa alubarika bi awon onimimo se se alaye re, leyinnaa o so nipa awon ipin wiwa alubarika eyi ti o pin si meji: eyi ti o leto ati eyi ti ko leto ti oro si tun waye lori awon nkan....
Diẹ ninu awọn Iranti Ọlọhun ti o wa lati ọdọ Ojisẹ Ọlọhun [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a] - (Èdè Yorùbá)
Diẹ ninu awọn iranti Ọlọhun ti o yẹ ki Musulumi o mọ ki o si maa se ni ojoojumọ lati inu iwe Husnul Muslim.
DIẸ NINU ADISỌKAN AWỌN ALASEJU NINU AWỌN SUUFI - (Èdè Yorùbá)
Akọsilẹ yii sọ diẹ ninu adisọkan awọn Suufi nipa ojisẹ Ọlọhun ati diẹ ninu adisọkan wọn nipa awọn ti a n pe ni waliyyul-lahi (Awọn ọrẹ Ọlọhun). A mu ọrọ naa wa lati inu tira “Almoosu’atul Muyassarah”.

API
