ISLAM ESIN GBOGBO OJISE.
ISLAM ESIN GBOGBO OJISE. - (Èdè Yorùbá)
TALODAMI ATIWIPE KINI ATORI E DA MI? - (Èdè Yorùbá)
TALODAMI ATIWIPE KINI ATORI E DA MI?
Baa sese Aluwala Tan manfi Eepe se - (Èdè Yorùbá)
Baa sese Aluwala Tan manfi Eepe se
Itumaa Kurani - (Èdè Yorùbá)
Itumaa Kurani
Igberun Duro - (Èdè Yorùbá)
Igberun Duro
Eko nipa Odun Itunu Aawe - (Èdè Yorùbá)
Olohun se ipari aawe ati ojo kewa osu Dhul-hijja ni odun fun awa Musulumi. Ibani soro yi n so nipa awon eko ti Islam ko wa nipa odun aawe. Ninu re ni ki Musulumi wo aso ti o dara ti o si wuyi ni ojo odun lati gbe ojo yi....
Amin Irole Aye - 1 - (Èdè Yorùbá)
Ibanisoro yi so nipa die ninu awon apeere ti a o fi maa mo nigbati opin aye ba n sunmo. Oniwaasi so ni ibere oro yi wipe gbigbe dide Anabi wa Muhammad je okan ninu awon apeere irole aye. Bakannaa ni oro wa lori sisokale Anabi Isa omo Maryam gege....
Amin Irole Aye - 2 - (Èdè Yorùbá)
Oniwaasi so ninu ibanisoro yi nipa awon apeere kekere ninu awon apeere irole aye, o si menu ba bi o se je wipe awon ti won je onimimo nipa oro Olohun yoo tan ni ori ile, ti iwa agbere yoo po, bakannaa ni oti mimu ati beebeelo.
Amin Irole Aye - 3 - (Èdè Yorùbá)
Oniwaasi so ninu ibanisoro yi nipa awon apeere kekere ninu awon apeere irole aye, o so nipa bi onka awon obinrin yoo se po ni awujo, bakannaa ni ki awon eniyan maa se afiti nkan si odo eni ti kii se eni ti o leto si i.
Amin Irole Aye - 4 - (Èdè Yorùbá)
Oniwaasi so ninu ibanisoro yi nipa awon apeere kekere ninu awon apeere irole aye, o so nipa wiwa imo nitori oro aye, ati bi okunrin yoo se maa tele ase iyawo re ti yoo si maa se aburu si iya re, bakannaa bi awon eniyan yoo se maa pariwo ninu....
Amin Irole Aye - 5 - (Èdè Yorùbá)
Oniwaasi so ninu ibanisoro yi nipa awon apeere kekere ninu awon apeere irole aye, gege bii ki awon eniyan maa se aponle okunrin kan nitori iberu aburu ise owo re. Leyinnaa o menu ba die ninu awon apeere irole aye ti o tobi, o si ka hadiisi ti Udhaefa gba....
Amin Irole Aye - 6 - (Èdè Yorùbá)
Oniwaasi soro nipa eranko kan ti Olohun yoo mu jade si awon eniyan ti yoo si maa ba awon eniyan soro gege bii okan ninu awon apeere irole aye ti o tobi. Bakannaa ni o so nipa yiyo oorun nibi ibuwo re, o si se afikun wipe ni asiko yi....

API
