Ibanisoro yi da lori idahun fun ibeere ti o n so pe: kinni idi ti Olohun fi da awa erusin Re? Oniwaasi si dahun ni kukuru wipe nitori ijosin ni Olohun fi da awa eniyan ati alijonnu. Oju ona kan soso ti a si fi le sin Olohun naa ni....
Kinni Idi ti Olohun fi da wa ? - (Èdè Yorùbá)
Ojuse Olori ati Awon ti won n dari ninu Islam - 1 - (Èdè Yorùbá)
Waasi yi so nipa bi o ti je wipe esin Islam menu ba gbogbo nkan patapata ti o fi de ibi eko bi a ti se n to tabi ya igbe, bawo ni Islam kose wa ni so nipa eto bi a se ndari ilu ati bi a se nse....
Ojuse Olori ati Awon ti won n dari ninu Islam - 2 - (Èdè Yorùbá)
Eleyi ni apa keji ibanisoro naa, olubanisoro nso eyi ti o ku ninu awon majemu ti o ye ki o wa fun eniti a fe fi se olori ninu Islam.
Alaye Lori Sunna Ati Pataki Re Nibi Agboye Esin - (Èdè Yorùbá)
Olubanisoro se ni alaye lekunrere nkan ti won npe ni Sunna, o so pelu akori wipe odidi esin Islam ni Sunna atipe Sunna gan an ni esin Islam. O tesiwaju ninu alaye re wipe agboye Alkurani ko rorun fun Musulumi bikose latari Sunna, bee si ni Sunna je aayan ongbifo....
Awon Nkan ti o nba Gbolohun Ijeri (La Ilaha Illa Allah) je - (Èdè Yorùbá)
Olubanisoro se alaye itumo gbolohun ijeri la ilaha illa Allah, o si tun so awon majemu ti o wa fun un ati awon nkan ti o maa nba gbolohun naa je.
Taani Olohun- 1 - (Èdè Yorùbá)
Olubanisọrọ bẹrẹ pẹlu alaye orisirisi awọn alajẹ ede ti awọn eniyan fun Ọlọhun Allah, o si tun se alaye nipa Eni ti o tọ ki a maa jọsin fun laiwa orogun pẹlu Rẹ Ohun naa ni Ọlọhun .O si tun tẹsiwaju ninu sise alaye ohun ti wọn npe ni At-Taoheed....
Taani Olohun- 2 - (Èdè Yorùbá)
Olubanisọrọ tẹsiwaju ninu alaye awọn nkan ti o maa nse akoba fun Taoheed ninu iran Ẹbọ sise ati okunfa re, gẹgẹ bii Mima se ijọsin nibi saare oku, Gbigbẹ saare si inu mọsalaasi, Tita ẹjẹ silẹ fun nkan miran ti o yatọ si Ọlọhun Allah, Wiwa idaabobo tabi iranlọwọ lọdọ....
Igbagbo Ninu Kadara - (Èdè Yorùbá)
Ibanisoro yi da lori alaye ni ekunrere nipa ohun ti a n pe ni kadara ati bi awon eniyan kan se sonu nitori re.
Alaye Itumo Aayah kẹtadinlaadọrun ninu Suuratul Bakọrah - (Èdè Yorùbá)
Itumọ aayah kẹtadinlaadọrun lati inu Suuratul Bakọrah eyi ti o da lori iroyin bi Ọlọhun Allah se se aranse fun Anọbi Isa ati bi awọn Yahuudi se tako igbedide Ojise Olohun Muhammad.
Idan ati Asasi -1 - (Èdè Yorùbá)
Ni apa yii, alaye waye nipa ipilẹ idan sise pẹlu iyatọ ti o nbẹ laarin oogun lilo ati idan.
Idan ati Asasi -2 - (Èdè Yorùbá)
Idajọ idan pẹlu awọn ẹri lati inu Alukuraani ati Sunna, awọn ijiya ti nbẹ fun opidan ati awọn adua isọ kuro nibi aburu awọn opidan.
Idan ati Asasi -3 - (Èdè Yorùbá)
Idajọ lilọ si ọdọ awọn opidan pẹlu awọn ibeere ati idahun olowo iye biye.

API
