"[1] Alaye ohun ti o njẹ iwa agbere ati wipe isẹ buburu ti Ọlọhun korira ni. [2] Diẹ ninu awọn oniranran aburu ti o rọ mọ iwa agbere.".
Aburu Iwa Agbere ( Sina ) - 1 - (Èdè Yorùbá)
Aburu Iwa Agbere ( Sina ) - 2 - (Èdè Yorùbá)
Ọrọ nipa awọn okunfa iwa agbere (sina) ati idahun si awọn ibeere.
( Imura Obinrin ti Islam pa lasẹ ( Al-hijab - (Èdè Yorùbá)
Alaye lẹkunrẹrẹ nipa ọsọ obinrin ati ọrọ lori ohun ti o njẹ Hijaabu.
Ẹkọ Ninu Igbesi Aye Iya wa Khadijah [Ki Ọlọhun yọnu si i] -1 - (Èdè Yorùbá)
Khadijah jẹ ẹniti awọn ara ilu Mẹkkah gba pe o mọ ninu awọn obinrin ki ẹsin Islam too de, oun si ni ẹni akọkọ ti o kọkọ gba Islam.
Ẹkọ Ninu Igbesi Aye Iya wa Khadijah [Ki Ọlọhun yọnu si i] -2 - (Èdè Yorùbá)
Diẹ ninu awọn iwa ti o rẹwa ti o n bẹ fun Iya wa Khadijah, ti wọn si tun sọ diẹ lara awọn ọla ti o n bẹ fun un.
Ẹkọ Ninu Igbesi Aye Iya wa Khadijah [Ki Ọlọhun yọnu si i] -3 - (Èdè Yorùbá)
Awọn ọla ti n bẹ fun Iya wa Khadijah, ti ibeere ati idahun si tẹle e.
Jijẹ Onisowo Musulumi Rere -1 - (Èdè Yorùbá)
Alaye lori itumọ owo sise pẹlu apejuwe rẹ ninu igbesi aye awọn Sahabe Anọbi [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a], lẹyin eyi ni ọrọ waye nipa idajọ Sharia lori owo sise.
Jijẹ Onisowo Musulumi Rere -2 - (Èdè Yorùbá)
Itẹsiwaju ninu alaye nipa idajọ Sharia lori owo sise, awọn ẹkọ ti o yẹ ki onisowo se amulo rẹ. Lẹyin eyi akiyesi waye lori awọn irori kan ti o pepe si atunse nipa owo sise.
Jijẹ Onisowo Musulumi Rere -3 - (Èdè Yorùbá)
Idahun si awọn ibeere ọlọkan-ọ-jọkan.
Alaye awọn ti wọn n sọ wipe Alukuraani nikan ni awọn ni Igbagbọ si. Kinni adisọkan wọn? Bawo ni awọn ijọ yii se sẹ yọ, ta si ni olori wọn
Alaye lori ibasepọ Sunnah ati Alukuraani, anfaani Sunnah nibi igbagbọye Alukuraani ati idahun si iruju awọn ijọ yii.
Idahun si iruju awọn ti wọn n sọ wipe Alukuraani nikan ni awọn ni Igbagbọ si (Al-Kur’aniyuun).

API
