Idanilẹkọ ti o n se alaye awọn nkan ti o n ba ẹsin jẹ mọ Musulumi lọwọ ti apa kan ninu awọn eniyan si n pe ni asa.
Asa ati Ẹsin - (Èdè Yorùbá)
Awọn Asa ti o ba Islam mu ati eyi ti o tako Islam - (Èdè Yorùbá)
Waasi oniyebiye ti o sọ nipa awọn asa ti o dara ti ẹsin Islam kin lẹyin, bakannaa awọn asa ti ko dara ti Islam kọ fun awa Musulumi.
Ẹtọ Adari ati Awọn ti wọn n dari - (Èdè Yorùbá)
Alaye lori awọn ojuse ati iwọ olori si awọn ti wọn ndari, bakannaa ojuse awọn ti wọn nse ijọba le lori si awọn adari
Titete fẹ Iyawo ninu Islam -1 - (Èdè Yorùbá)
Alaye lori awọn nkan ti wọn fẹ ki ekeni-keji ọkọ ati iyawo wo lara ara wọn ki o too di wipe eto igbeyawo waye.
Titete fẹ Iyawo ninu Islam -2 - (Èdè Yorùbá)
Aworan igbeyawo awọn Saabe pẹlu anfaani ti o wa nibi titete fẹ iyawo.
Titete fẹ Iyawo ninu Islam -3 - (Èdè Yorùbá)
Idahun si awọn ibeere ọlọkan-ọ-jọkan.
Pataki awọn Sọhaba nipa wipe ẹni abiyi ni wọn ati itan ọkan ninu awọn Sọhaba eyi tii se Sa’eed ibn ‘Aamir Al-Jumahi [Ki Ọlọhun yọnu si i].
Itẹsiwaju ọrọ lori itan Sa’eed ibn ‘Aamir Al-Jumahi [Ki Ọlọhun yọnu si i].
Awọn Okunfa ti o n da Igbeyawo ru - (Èdè Yorùbá)
Itumọ idile alayọ ati ajọse ti o yẹ ki o wa laarin ọkọ ati iyawo rẹ, pẹlu imọran lori bi o se yẹ ki ọkọ maa se daradara si awọn ara ile rẹ.
Awọn Iwa Rere ati Anfaani rẹ - (Èdè Yorùbá)
Alaye lori Pataki iwa rere ati ipo ti o maa n gbe eniyan de ni iwaju Ọlọhun pẹlu imọran lori sise gbogbo isẹ oloore.
Dida Ebi Po - (Èdè Yorùbá)
Olubanisoro se alaye ohun ti o nje ebi, o si se alaye bakannaa bi o se ye ki eniyan maa da ebi re po. O tun se afikun anfaani ti o wa nibi ki eniyan maa da ebi po ati ijiya ti o wa nibi ki eniyan maa ja okun....
Ifeto si Ọmọ Bibi, Ifopin si Ọmọ Bibi, ati Oyun Sisẹ -1 - (Èdè Yorùbá)
Ibanisọrọ yi se alaye awọn koko wọnyi: (1) Iyatọ laarin ifeto sọmọ bibi ati ifopin sọmọ bibi. (2) Awọn ẹri pe Islam se wa lojukokoro lori ọmọ bibi. (3) Itan igba ti irori fifi opin si ọmọ bibi bẹrẹ.

API
