Ni abala yii ni awọn idahun ti waye si awọn ibeere lori idanilẹkọ naa.
Taani Aafa (Alufa)? -3 - (Èdè Yorùbá)
Atubọtan-1 - (Èdè Yorùbá)
Alaye itumọ ohun ti a mọ si atubọtan ati awọn isẹ ti o maa nfa atubọtan buruku fun eniyan.
Atubọtan-2 - (Èdè Yorùbá)
Ninu apa yii alaye waye lori awọn iwa tabi isesi ti o maa nfa atubọtan buruku fun eniyan.
Atubọtan-3 - (Èdè Yorùbá)
Ni apa yii alaye wa lori okunfa atubọtan daadaa fun eniyan pẹlu awọn apẹẹrẹ ti a o ri lara eniyan, ti njuwe pe iru ẹni bayi ni atubọtan daadaa.
Ọrọ nipa bi sise ajọdun ọjọ ibi Anabi (Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki maa ba a) se bẹrẹ.
Oludanilẹkọ sọ ni apa yii ọrọ awọn aafa ti wọn sọ wipe ko si laifi nibi sise ayẹyẹ ọjọ ibi Anabi (Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki maa ba a).
Oludanilẹkọ sọ ni apa yii ọrọ awọn aafa ti wọn sọ wipe adadasilẹ sise ni ayẹyẹ ọjọ ibi Anabi (Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki maa ba a) pẹlu awọn ẹri ti wọn fi rinlẹ lori awọn ọrọ wọn.
Abala yii ni abala ibeere ati idahun.
Ojuse Asiwaju Si Awọn Ọmọlẹyin - (Èdè Yorùbá)
Alaye bi ẹsin Islam se pa asiwaju ni asẹ lati maa se ojuse rẹ lori awọn ọmọlẹyin rẹ, pẹlu apejuwe igbesi aye saabe agba Umar bin Khataab [Ki Ọlọhun Kẹ ẹ]
Pataki Sise Adua Fun Ilu Ẹni - (Èdè Yorùbá)
Idanilẹkọ nipa awọn okunfa gbigba adua, ati wipe ẹniti o ba ni ifẹ si ilu rẹ gbọdọ maa se adua ki ilu naa dara.
Iduro sinsin - (Èdè Yorùbá)
Akori ibanisọrọ da lori wipe iduro sinsin jẹ ẹmi gbogbo awọn isẹ ijọsin patapata. Idahun si awọn ibeere olowo-iye-biye nipa ibanisọrọ ti o waye lori Iduro sinsin.
Itoju Awon Obi Mejeeji - (Èdè Yorùbá)
Waasi yi so nipa pataki sise daradara si awon obi mejeeji ati bi Olohun ti se e ni dandan fun omo eniyan, beeni o tun se alaye esan nla ti o wa nibi ki eniyan maa se itoju won ati aburu ti o wa nibi sise aidaa si won.

API
