Idanilẹkọ yii da lori awọn ọna ti musulumi fi le wa isọ Ọlọhun ati aabo Rẹ gẹgẹ bii: Jijẹ eso dabidun ‘ajiwa, sise aluwala loore koore, mima ki irun Fajri ni jama’a, mima ki irun oru, ati bẹẹ bẹẹ lọ.
Awọn Ọna ti o ba Ẹsin Islam mu fun Isọ Ọlọhun ati Aabo Rẹ - (Èdè Yorùbá)
Awọn Ohun Eewọ ti apakan ninu awọn Musulumi fi ọwọ yẹpẹrẹ mu - (Èdè Yorùbá)
Idanilẹkọ nipa awọn ohun eewọ ti o ti di gbajumọ ni awujọ wa ni ode oni pẹlu ẹri ikilọ awọn iwa ibajẹ yii lati inu Alukuraani ati Sunnah Anabi.
Idajọ Ẹsin lori Rukiya, Oogun Ifẹ ati Gbekude lilo - (Èdè Yorùbá)
Idanilẹkọ yii da lori awọn koko wọnyii: (i) Iha ti ẹsin ko si Rukiya, Oogun ifẹ ati Gbekude lilo, (ii) Idajọ awọn nkan mẹtẹẹta yii, (iii) Majẹmu Rukiya, (iv) Idajọ wiwe ayah Alukuraani ati dide mọ ọrun, (v) Diẹ ninu awọn Rukiya ti a le fi se isọ fun alaarẹ,....
Pataki sise Isẹ tọ Imọ - (Èdè Yorùbá)
Alaye erenjẹ ti o wa fun lilo Imọ ati Ibalẹjọ ti o wa fun ki eniyan ma lo Imọ.
Alaye nipa Ẹjẹ nkan-osu Obinrin, Ẹjẹ Awọọda ati Ẹjẹ Ibimọ - (Èdè Yorùbá)
Alaye ati idajọ lori ohun ti o nii se pẹlu Ẹjẹ Alaada (nkan-osu Obinrin). Idanilẹkọ ni abala yii da lori alaye ati idajọ ti o rọ mọ Ẹjẹ Awọọda ati Ẹjẹ Ibimọ.
Pataki Iranti Ọlọhun - (Èdè Yorùbá)
Idanilẹkọ yii sọ nipa awọn ẹsan ati pataki sise iranti Ọlọhun.
Pataki Adua ati Anfaani rẹ - (Èdè Yorùbá)
Khutuba yii da lori pataki adua sise ati anfaani to wa nibi adua sise Itẹsiwaju alaye lori pataki adua sise
Sise Ọlọhun ni Ọkan Soso nibi Awọn Orukọ Rẹ ati Iroyin Rẹ - (Èdè Yorùbá)
1- Awọn akori ọrọ ti o jẹyọ ni abala yii ni wọnyii: (i).Itumọ sise Ọlọhun ni Ọkan soso nibi Awọn Orukọ Rẹ ati Iroyin Rẹ. (ii). Alaye lori awọn ti wọn lodi si Sunna nibi ilana yii. 2- Alaye nipa ilana awọn ti won tẹle Sunna nibi orukọ Ọlọhun ati....
Ọla ti n be fun Imọ ati bukaata ti a ni si i - (Èdè Yorùbá)
Alaye lori ajulo, ẹsan ati pataki ti n bẹ nibi nini imọ ẹsin pẹlu ẹri rẹ lati inu Alukuraani ati Sunnah.
Awọn asikiri ti a maa sọ ni owurọ ati aṣalẹ - (Èdè Yorùbá)
Awọn asikiri ti a maa sọ ni owurọ ati aṣalẹ
Tira kékeré kan nipa awọn ẹjẹ adamọ fun awọn obinrin - (Èdè Yorùbá)
Tira kékeré kan nipa awọn ẹjẹ adamọ fun awọn obinrin
Isọrọ perengede lori pipe Shariah ati ewu dida adadaalẹ - (Èdè Yorùbá)
Isọrọ perengede lori pipe Shariah ati ewu dida adadaalẹ

API


