Óró Nipa Ifin tin jè Igbaa gbó odoo doo Nipa Awan Malaika mani
Óró Nipa Ifin tin jè Igbaa gbó odoo doo Nipa Awan Tirara towa lat
Óró Nipa Ifin tin jè Igbaa gbó odoo doo Nipa Awan Ojisé é Alla
Igbagbọ ni ọjọ ikẹhin - (Èdè Yorùbá)
Igbagbọ ni ọjọ ikẹhin
Igbagbọ ninu aṣẹ Ọlọrun - (Èdè Yorùbá)
Igbagbọ ninu aṣẹ Ọlọrun
Apa keji yi so nipa awon nkan wonyi: (1) Awon eko ti o dara julo ti o wa nibi ibasepo Ojise Olohun pelu awon Saabe re. (2) Sise awon Musulumi ni ojukokoro sibi kikose Ojise Olohun nibi awon iwa re fun oore aye ati orun.
Waasi yi je idahun fun awon ibeere wonyi: (1) Kinni paapaa itumo fiferan Ojise Olohun? (2) Kinni idi ti Olohun fi royin Ojise Re pelu iwa rere nibi ti O ti so wipe: {Dajudaju ire (Anabi) ni o ni iwa ti o dara julo}. (3) Tani eni ti o je....
Oju-ona si Ogba Idera (Al-janna) - 2 - (Èdè Yorùbá)
Oniwaasi se alaye ni abala yi wipe ti awon onimimo esin ba nso oro nipa awon ijo ti yoo la ti yoo ba ojise Olohun wo Al-janna itumo re ni wipe awon ti won ba ntele ilana ojise naa, kiise gbogbo eniti o ba npe ara re ni oni sunna,....
Oju-ona si Ogba Idera (Al-janna) - 1 - (Èdè Yorùbá)
Waasi yi da lori awon nkan ti yo maa je atona fun Musulumi losi ogba idera Al-janna, alakoko re ni adiokan ti o dara ti o jinna si ebo, eleekeji si ni ijosin ti o ni alaafia ti o wa ni ibamu pelu eyi ti ojise Olohun se.
NJE A LE RI ANABI NI OJU ALA? - (Èdè Yorùbá)
Akosile yi da lori bi eniyan kan se le ri anabi wa Muhammad- ki ike ati ola Olohun maa ba a- ti yoo si mo wipe anabi gan an ni oun ri, bakannaa o se alaye bi o se je wipe awon eniyan kan maa n ri Esu [Shatani] ti....
Alaye lẹkunrẹrẹ nipa ohun ti o rọ mọ sisọkalẹ Anabi Isa [ Ọla Ọlọhun ki o maa ba a ].
1- Itan Iya Anọbi Isa [Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a] ati itan iya-iya rẹ. 2- Alaye bi wọn se ni oyun Anọbi Isa [Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a] ni ọna iyanu pẹlu bibi rẹ ni ọna iyanu, ti eleyi ko si sọ....