1- Alaye nipa aayah Alukuraani ti o wa lori asalaatu sise fun Anọbi [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a], pataki asalaatu ati wipe bawo ni o se yẹ ki a maa se. 2- Pataki sise asalaatu fun Anabi [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a]....
Ojuse awa Musulumi si Anabi wa Muhammad [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a] da lori awọn koko wọnyii: 1. Titẹle asẹ rẹ. 2. Gbigba ọrọ rẹ gbọ ni ododo. 3. Kikọse rẹ ninu iwa, ẹsin ati isesi. 4. Ninifẹ rẹ pẹlu mimaa se asalaatu fun un, ati....
Ọranyan titẹle Asẹ Ọlọhun Allah ati Asẹ Ojisẹ - (Èdè Yorùbá)
Idanilẹkọ yi da lori wipe titẹle asẹ Ọlọhun ati asẹ Ojisẹ Rẹ (ike ati ola Ọlọhun ki o maa ba a) ni ojulowo ẹsin. Alaye si tun waye nipa wipe sise ọjọ ibi Anọbi (Maoludi Nabiyi) ko ba ofin ẹsin Islam mu pelu awọn ẹri.
NJE A LE RI ANABI NI OJU ALA? - (Èdè Yorùbá)
Akosile yi da lori bi eniyan kan se le ri anabi wa Muhammad- ki ike ati ola Olohun maa ba a- ti yoo si mo wipe anabi gan an ni oun ri, bakannaa o se alaye bi o se je wipe awon eniyan kan maa n ri Esu [Shatani] ti....
Awon Eko Pataki Nibi Ogun Khandak - (Èdè Yorùbá)
Alaye ohun ti o se okunfa ogun yii ati awon isele ti o waye nibi sise ipalemo fun ogun naa eyi ti o je eri ododo lori wipe Annabi Muhammad ojise Olohun ni. Alaye si tun waye lori aranse ti Olohun se fun ojise Re ninu ogun naa.