Akosile yi da lori bi eniyan kan se le ri anabi wa Muhammad- ki ike ati ola Olohun maa ba a- ti yoo si mo wipe anabi gan an ni oun ri, bakannaa o se alaye bi o se je wipe awon eniyan kan maa n ri Esu [Shatani] ti....
NJE A LE RI ANABI NI OJU ALA? - (Èdè Yorùbá)
Idajọ Kiki Pẹlu Titẹ ati Idọbalẹ Ninu Islam - (Èdè Yorùbá)
Alaye lori wipe kiki eniyan pẹlu titẹ ati idọbalẹ kosi ninu ohun ti ẹsin Islam gba Musulumi laaye lati se.
Ninu Awon Eko Irinajo fun Ise Haj Tabi Umrah - (Èdè Yorùbá)
Wiwa ojurere Olohun, kiko awon ese sile, siso enu aala Olohun, didunni mo iranti Olohun ati beebee lo ni awon eko ti akosile yi so nipa won. Eleyi si ni die ninu awon ojuse Musulumi ti o ba gbero lati se irinajo fun ise Haj tabi Umrah.
Siso Ahan Ati Awon Ohun Ti O Le Ran Musulumi Lowo Lori Re - (Èdè Yorùbá)
Pataki ahon ninu awon eya ara eniyan, siso ahan nibi awon ohun ti ko ye ki Musulumi maa fi se ati awon ohun ti o le se iranlowo fun Musulumi lati so ahan re, gbogbo awon nkan wonyi ni akosile yi gbe yewo.
Sisọ Ahọn ati bi o ti se Pataki to - (Èdè Yorùbá)
Pataki sisọ ohun ti n jade ni ẹnu ọmọniyan ati ẹsan ti o wa nibi sisọ ahọn.
Awọn Ẹkọ ti o nbẹ fun jijẹ ati mimu - (Èdè Yorùbá)
1- Ninu abala yi ọrọ waye lori wipe ounjẹ ti Ọlọhun Allah pese fun wa idẹra ni o jẹ ati alaye idi ti o fi jẹ idẹra. Bakannaa awọn nkan ti o dara pupọ lati se akiyesi rẹ nigba ti a ba fẹ jẹ ounjẹ. 2- Abala yii jẹ itẹsiwaju....
Awọn Ẹko ti o rọ mọ Ọmọ-ọdọ tabi Osisẹ ti a gba si isẹ - (Èdè Yorùbá)
Alaye ni ẹkunrẹrẹ waye ninu idanilẹkọ yii lori ẹkọ ti o rọ mọ gbogbo ẹni ti n se isẹ sin eniyan.
Ẹkọ nipa Apejẹ igbeyawo (Walimatu-Nikah) - (Èdè Yorùbá)
Idanilẹkọ yi sọ nipa idajọ ki eniyan se ounjẹ lati fi ko awọn eniyan lẹnu jọ ati bẹẹ bẹẹ lọ ninu awọn ẹkọ ti o rọ mọ apejẹ sibi igbeyawo (walimọtu- nikahi).
Ninu Awọn Ẹkọ Irinajo - (Èdè Yorùbá)
1- Ninu abala yi ọrọ waye lori awọn nkan ti o ye ki arinrinajo se ki o to bẹrẹ irinajo rẹ. 2- Ninu abala yi ọrọ waye lẹkunrẹrẹ lori awọn ẹkọ ti o yẹ ki arinrinajo maa mu lo ni asiko ti ba nse irinajo rẹ.
Awọn Aaye ti a kọ fun wa lati kirun nibẹ - (Èdè Yorùbá)
Alaye nipa awon aaye ti ko leto ki Musulumi ki irun nibe gege bii ite oku ati ile egbin.