×
Image

DIẸ NINU ADISỌKAN AWỌN ALASEJU NINU AWỌN SUUFI - (Èdè Yorùbá)

Akọsilẹ yii sọ diẹ ninu adisọkan awọn Suufi nipa ojisẹ Ọlọhun ati diẹ ninu adisọkan wọn nipa awọn ti a n pe ni waliyyul-lahi (Awọn ọrẹ Ọlọhun). A mu ọrọ naa wa lati inu tira “Almoosu’atul Muyassarah”.

Image

Pataki Adua ninu Islam - (Èdè Yorùbá)

Akọsilẹ ti o sọ nipa anfaani ti o n bẹ nibi adua fun Musulumi ododo ati bi o se jẹ ohun ti Ọlọhun fẹran lati ọdọ ẹru Rẹ.

Image

AKASO ODODO (Al- WASEELAH) - (Èdè Yorùbá)

Idanileko yii so nipa ohun ti a npe ni akaso ododo tabi wiwa ategun si odo Olohun eyi ti esin Islam pawa lase re. Oro die waye nipa awon eri lori bi a tise nwa ategun ati die ninu asise ti apakan ninu awon Musulumi maa nse

Image

Ikuro ninu Ẹsin ati Okunfa rẹ - (Èdè Yorùbá)

Itumọ kikuro ninu ẹsin Islam (Ar-Rida). Awọn nkan ti ọmọniyan yoo se ti idajọ kikuro ninu ẹsin yoo fi sẹ le lori. Idajọ kikuro ninu ẹsin Islam (kikoomọ) ati awọn diẹ ninu ise ti eniyan le se ti yoo se okunfa kikuro ninu ẹsin Islam. Itẹsiwaju ninu alaye awọn okunfa....

Image

Alaye Awọn Opo Islam Maraarun - (Èdè Yorùbá)

Alaye ọrọ lori awọn opo ẹsin Islam maraarun pẹlu bi ikọọkan wọn se ni ipan to ati ewu ti o wa ninu fifi ọwọ yẹpẹrẹ mu wọn.

Image

Igbagbọ Ijọ Shia – 1 - (Èdè Yorùbá)

Alaye nipa bi Ijọ Shia se bẹrẹ pẹlu itọkasi wipe Yahuudi ni ẹni ti o pilẹ Ijọ Shia.

Image

Igbagbọ Ijọ Shia – 2 - (Èdè Yorùbá)

Alaye ni ẹkunrẹrẹ nipa adiọkan awọn Ijọ Shia: Adiọkan wọn nipa awọn Saabe Ojise Ọlọhun [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a], adiọkan wọn si Alukuraani ati bẹẹbẹẹ lọ.

Image

Igbagbọ Ijọ Shia – 3 - (Èdè Yorùbá)

Diẹ nipa ete awọn Ijọ Shia fun awa Musulumi ti a wa lori Sunna Anabi wa Muhammad [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a].

Image

Aseju ninu Ẹsin -1 - (Èdè Yorùbá)

Alaye ohun ti njẹ aseju ninu ẹsin, ipilẹ ati paapaa aseju ninu ẹsin ati awọn apejuwe rẹ.

Image

Aseju ninu Ẹsin -2 - (Èdè Yorùbá)

Ọrọ nipa awọn okunfa aseju ninu ẹsin ati awọn ohun ti o le dẹkun tabi fi opin si sise aseju ninu ẹsin Islam.

Image

Hadiith ogoji ti o je ti Alufa wa Nawawiy - (Èdè Yorùbá)

Hadiith ogoji ti o je ti Alufa wa Nawawiy