×
Image

Se pẹlu agbara ni o yẹ ki a fi bẹrẹ lati se atunse iwa ti ko dara bi? - (Èdè Yorùbá)

Idahun lori bi o se jẹ wipe sise ayipada isesi tabi iwa ti ko dara wa ni ipele ipele.

Image

Idajọ Nina Ọmọ Akẹkọ L’obinrin - (Èdè Yorùbá)

Idajọ fifi iya jẹ ọmọ akẹkọ l’obinrin pẹlu lilu u ni ẹgba, ti o si jẹ wipe o rọrun lati se itọsọna fun un pẹlu ọrọ ẹnu.

Image

Sise Isẹ Ijọsin Umrah ninu Osu Rajab - (Èdè Yorùbá)

Alaye bi o se jẹ wipe adadasilẹ ninu ẹsin ni ki Musulumi ni adisọkan wipe isẹ ijọsin Umrah ninu osu Rajab ni ọla kan ti o yatọ si asiko miran.

Image

Lilo Oruka Fadaka ninu Osu Rajab - (Èdè Yorùbá)

Idajọ ki Musulumi maa lo oruka ti wọn fi fadaka se pẹlu adisọkan ti ko dara.