Apa keji yi so nipa awon nkan wonyi: (1) Awon eko ti o dara julo ti o wa nibi ibasepo Ojise Olohun pelu awon Saabe re. (2) Sise awon Musulumi ni ojukokoro sibi kikose Ojise Olohun nibi awon iwa re fun oore aye ati orun.
Ohun ti o ye ki Musulumi mo nipa Suufi - (Èdè Yorùbá)
Ibanisọrọ yii da lori awọn osuwọn tabi awọn ojupọnan ti Musulumi gbọdọ maa gbe isẹ ẹsin rẹ le ki o le jẹ atẹwọgba lọdọ Ọlọhun Allah.
Pataki Alukuraani ati Titobi Rẹ - 1 - (Èdè Yorùbá)
Ninu apa kinni yi: (1) Oro nipa awọn orukọ, iroyin ati awọn ẹwa ti Ọlọhun fi se iroyin Alukuraani. (2) Awọn ọla ti nbẹ fun Alukuraani. (3) Awọn ẹkọ ti o wa fun kika Alukuraani ati ọla ti nbẹ fun Olumọ Alukuraani.
Pataki Alukuraani ati Titobi Rẹ - 2 - (Èdè Yorùbá)
Alaye awọn nkan ti o le ran Musulumi lọwọ lati jẹ Olumọ Alukuraani pelu ibeere ati idahun.
Awọn Okunfa Lilekun ati Didinku Igbagbọ-1 - (Èdè Yorùbá)
Idanilẹkọ yii bẹrẹ pẹlu sisọ itumọ igbagbọ pẹlu orisi ọna ti a le gbọ ọ ye si, yala ninu adisọkan ni, tabi wiwi jade ni ẹnu, tabi fifi sisẹ se.
Awọn Okunfa Lilekun ati Didinku Igbagbọ-2 - (Èdè Yorùbá)
Abala yii se alaye wipe Igbagbọ maa nlekun, o si maa ndinku pẹlu awọn ẹri lati inu Alukuraani ati Hadisi.
Awọn Okunfa Lilekun ati Didinku Igbagbọ-3 - (Èdè Yorùbá)
Abala yii se ifọsiwẹwẹ awọn nkan ti o maa nse alekun igbagbọ musulumi pẹlu alaye rẹ.
Awọn Okunfa Lilekun ati Didinku Igbagbọ-4 - (Èdè Yorùbá)
Abala yii jẹ idahun si awọn ibeere olowo-iye-biye ti o waye ni ipari idanilẹkọ naa.
Taani Aafa (Alufa)? -1 - (Èdè Yorùbá)
Ninu idanilẹkọ yii ọrọ waye nipa itumọ Aafa tabi Alufa ninu ede ati ni oniranran ọna ti a fi le gbọ itumọ rẹ ye, pẹlu itọka si awọn amin ti a fi le da Aafa mọ ni awujọ.
Taani Aafa (Alufa)? -2 - (Èdè Yorùbá)
Ni abala yii, ọrọ waye lori awọn ohun isami Aafa ni ọdọ awọn ẹya Yoruba pẹlu awọn oniranran apẹrẹ ẹni ti awọn Yoruba ka kun onimimọ.
Taani Aafa (Alufa)? -3 - (Èdè Yorùbá)
Ni abala yii ni awọn idahun ti waye si awọn ibeere lori idanilẹkọ naa.
Atubọtan-1 - (Èdè Yorùbá)
Alaye itumọ ohun ti a mọ si atubọtan ati awọn isẹ ti o maa nfa atubọtan buruku fun eniyan.

API
