Awón Ton baa Aluwala jé
Awón Ton baa Aluwala jé - (Èdè Yorùbá)
Awón Inkan Too dan dan ni bii Ikirun - (Èdè Yorùbá)
Awón Inkan Too dan dan ni bii Ikirun
Óró Nipa Imaa Anabiwa Muhammad - (Èdè Yorùbá)
Óró Nipa Imaa Anabiwa Muhammad
Tani Olorun ninu Islam? - (Èdè Yorùbá)
Tani Olorun ninu Islam?
Óró Nipa Ifin tin jè Islam mani Ati Ala - (Èdè Yorùbá)
Óró Nipa Ifin tin jè Islam mani Ati Ala
Kini An Peni Imo Olohun Lokan - (Èdè Yorùbá)
Kini An Peni Imo Olohun Lokan
Awon Oro Ibeere Merin - (Èdè Yorùbá)
Awon Oro Ibeere Merin
NJE A LE RI ANABI NI OJU ALA? - (Èdè Yorùbá)
Akosile yi da lori bi eniyan kan se le ri anabi wa Muhammad- ki ike ati ola Olohun maa ba a- ti yoo si mo wipe anabi gan an ni oun ri, bakannaa o se alaye bi o se je wipe awon eniyan kan maa n ri Esu [Shatani] ti....
Alaye lori Aayah (23) ninu Suuratu Furkooni - (Èdè Yorùbá)
Ise ijosin eyi ti erusin Olohun yoo maa ni esan lori re naa ni eyi ti o ba je wipe onigbagbo ododo ti o si n tele ilana anabi Muhammad ni o se e, sugbon eyi ti o ba je ti alaigbagbo ofo ati adanu ni yoo je ere re.
Sise daadaa si awon obi je ojuse Pataki ti Olohun pa omo ni ase re leyin ti o pase wipe ko gbodo josin fun nkan miran yato si Oun Olohun. Eleyi ni ohun ti ibanisoro yi da lelori, olubanisoro si mu awon apejuwe lori oore ti o wa ninu ki....
Agboye Esin Islam - (Èdè Yorùbá)
Ibanisoro yi so nipa bi esin Islam se je esin ti o dasi igbesi aye eniyan patapata ti kii se nipa ohun ti o nse ninu mosalaasi nikan. Olubanisoro si menu ba itumo Islam, beenaani o so ewu ti o nbe nibi ki eniyan maa tele awon eniyan kan lori....
Pataki Adua - (Èdè Yorùbá)
Ibanisoro yi da lori adua ati pataki re. Adua ni ohun ti o je oranyan fun Musulumi lati maa se nigbakiigba ti o ba nfe nkan, ki o si doju adua naa ko Olohun re, ki o mase pe elomiran ayafi Oun.

API

