×
Image

Alaye Aaya kẹjọ ati ẹkẹsan ninu Suuratul Mumtahinah - (Èdè Yorùbá)

Ohun ti o waye ninu ibanisọrọ yii: (1) Sise daadaa si aladugbo ti kiise Musulumi. (2) Ki ọmọ maa se daadaa si awọn obi rẹ mejeeji ti wọn kiise Musulumi.

Image

Awọn ohun ti kii jẹ ki Adua o gba - (Èdè Yorùbá)

Akosile ti o da lori awon nkan ti apa kan ninu awon Musulumi maa n se ti o maa n se okunfa ki Olohun ma gba adua won

Image

Ojuse Musulumi si Ẹbi rẹ - (Èdè Yorùbá)

Akọsilẹ ti o n sọ nipa itumọ okun ibi, lẹhinnaa o tun se alaye ni ekunrẹrẹ awọn oore ti o wa nibi sise daadaa si awọn ẹbi ati aburu ti o wa nibi jija okun ẹbi.

Image

Sise Isẹ Ijọsin Umrah ninu Osu Rajab - (Èdè Yorùbá)

Alaye bi o se jẹ wipe adadasilẹ ninu ẹsin ni ki Musulumi ni adisọkan wipe isẹ ijọsin Umrah ninu osu Rajab ni ọla kan ti o yatọ si asiko miran.

Image

Ninu Awọn Okunfa Adadasilẹ - (Èdè Yorùbá)

Alaye nipa diẹ ninu awọn nkan ti o maa n se okunfa ki adadasilẹ tan kan ni awujọ gẹgẹ bii kikọlẹ awọn onimimọ lati fi ododo ẹsin mọ awọn eniyan, ati bẹẹ bẹẹ lọ

Image

Awọn Nkan ti Apa kan Ninu Awọn Musulumi fi maa n bura Yatọ si Ọlọhun - (Èdè Yorùbá)

Akọsilẹ ti o sọ diẹ ninu awọn nkan ti apa kan ninu awọn alaimọkan Musulumi fi maa n se ibura ti o si lodi si ilana ẹsin Islam.

Image

Lilo Oruka Fadaka ninu Osu Rajab - (Èdè Yorùbá)

Idajọ ki Musulumi maa lo oruka ti wọn fi fadaka se pẹlu adisọkan ti ko dara.

Image

Ọna ti A le gba ri Owo ati Ọna nina rẹ ninu Islam - 1/ 3 - (Èdè Yorùbá)

Pataki owo ati wipe wiwa owo gbọdọ jẹ lati ọna ti o mọ ti o si jẹ ẹtọ

Image

Ọna ti A le gba ri Owo ati Ọna nina rẹ ninu Islam - 2/ 3 - (Èdè Yorùbá)

Awọn ọna ti a le gba ko arisiki jọ pẹlu awọn ẹri wọn lati inu Alukuraani ati Sunnah.

Image

Ọna ti A le gba ri Owo ati Ọna nina rẹ ninu Islam - 3/ 3 - (Èdè Yorùbá)

Itẹsiwaju ninu alaye ọrọ lori awọn ọna ti a le gba ko arisiki jọ.

Image

Ẹkunrẹrẹ Ẹkọ nipa Oku - 1/ 5 - (Èdè Yorùbá)

Ipalese silẹ siwaju ki iku too de, ati awọn ojuse wa si ẹni ti npọka iku lọwọ pẹlu awọn ojuse wa si ẹni ti ẹmi sẹsẹ jade lara rẹ

Image

Ẹkunrẹrẹ Ẹkọ nipa Oku - 2/ 5 - (Èdè Yorùbá)

Awọn isesi ti a kọ fun ẹni ti ọfọ ba sẹ, ati sise alaye diẹ nipa awọn ẹkọ ti o rọ mọ oku wiwẹ.